Ẹ̀rè ìdárayá AfroBasket 2025: D’Tigress ti ṣẹgun Cameroon pelu ami 83–47, yoo ba Senegal ṣere ni idije idaji ikẹhin.